We Are The Charleans

International News - A Yoruba Perspective

From BBC


Ọba fi àmì ẹ̀yẹ dá akínkanjú ìbejì tó dóòlà èkejì rẹ̀ lọ́wọ́ ọ̀ọ̀nì lọ́lá
Georgia Laurie ẹni ọdun mọkanlelọgbọn da ẹṣẹ bo ọọni loju nigba ti ọọni naa kọlu Melissa Laurie ekeji rẹ nigba ti wọn n wẹ ninu odo kan ni Mexico lọdun 2021.

Ìdí tí èèyàn fi fẹ́ràn láti máa jẹ ìpápánu dípò oúnjẹ
Jíjẹ oúnjẹ tàbí ìpápánu láì ṣe wí pé ebi ń pa èèyàn ni àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì pè ní “hedone” èyí tó jẹyọ láti inú èdè Gíríkì tó túmọ́ sí “mímu”.

Mo ti ṣetán láti gorí ìtẹ́ Olubadan -Olakuleyin
Ẹni ti ireti wa pe yoo jọba ilu Ibadan bayii, Alagba Owolabi Ọlakulẹyin,ti sọ pe tabi ṣugbọn kan ko si, oun ni ipo Olubadan kan.

Ìdí tí mi ò fi ń kópa nínú eré ṣíṣe mọ́ rèé - Sanyẹri
‘’Awọn eeyan le jẹri mi pe mi o ki i gba oko ere kan de omi-in. Bii ki ẹnikan sare pe mi pe ki n waa ba oun kopa abala bii mẹta, ti mo si wa ni lokeṣan kan lọwọ.

‘Àwọn láńlọọ̀dù kọ̀ láti fún mi nílé nítorí n kò rẹwà lọ́mọbìnrin’
Ṣugbọn bi nnkan ṣe ri bayii, awọn ọdọmọbinrin kan n la oriṣiriṣi iṣoro kọja lati ni ile lori ni Naijiria.

Ẹ̀sùn owó orí ìyàwó sísan fa ikú èèyàn mẹ́ta, gbé èèyàn méje dọ́gbà ẹ̀wọ̀n
Àwọn ọlọ́pàá ní bí wọ́n ṣe gbé òkú Anshika kúrò nínú ilé àwọn Anshu ni àwọn ẹbí rẹ̀ dáná sí ilé náà.

Ilé-ẹjọ́ dá gbajúmọ̀ Dókítá oníṣẹ́-abẹ ìdí lẹ́bi l’Ekoo
Ṣaa, lẹyin ọdun mẹrin ti ọrọ naa ti wa nilẹ, Amofin Irukera ti i ṣe ọga FCCPC tẹlẹ, sọ lọjọ Ẹti, ọjọ kẹtadinlogun oṣu karun-un 2024, pe kootu ti fidi ẹ mulẹ pe Dokita Aanu jẹbi awọn ẹsun ti wọn fi kan an.

"Ta ni ọ́ láti dá wa lẹ́jọ́ pé ara wa dọ̀tí torí a ya Tatoo, ìwúrí ni fún ọ̀pọ̀ èèyàn?"
BBC bá àwọn obìnrin Thai tó ń ya Tàtúù sí ara sọ̀rọ̀, tí ọ̀pọ̀ wọ́n sì ń fọnmú lórí bí àwọn èèyàn kan ṣe ń tàbùkù wọn nígbà tí àwọn mìí ń ṣe ìwúrí fún wọn.

'Kò sí àǹfàní kankan tí à ń rí, òṣì àti ìṣẹ́ la fi ń lo ayé wa'
Ko si awọn nnkan amayedẹrun niluu naa, eyi to n jẹ k'awọn alaboyun to ba fẹ bímọ maa rinrin ajo lọ sibi to jinna lati lọ bimọ.

Wọ́n ti sin òkú gbajúmọ̀ òṣèré nì, Junior Pope
Ṣáájú ni Rollas ti kọ́kọ́ kéde pé Junior Pope ṣì wà láyé lẹ́yìn ìròyìn ikú rẹ̀ gba orí ayélujára.

Iye àwọn tó ti kú nínú ìṣẹ̀lẹ̀ mọ́ṣáláṣí tí ọmọkùnrin kan dáná sun ní Kano ti di márùndínlógún
Olugbe agbegbe naa ti orukọ rẹ n jẹ, Hamisu Abdullahi sọ fun BBC pe eeyan mẹjọ lara awọn to gbẹmi mi nitori iṣẹlẹ naa ni wọn ti ṣe eto isinku fun wọn.

Binance tún lúlẹ̀ ní Nàìjíríà, ile ẹjọ́ ní kò sí àyè béèlì fún òṣìṣẹ́ rẹ̀ tó ń jẹ́jọ́ EFCC
Igbẹjọ lori kiko owo kuro lorilẹede Naijiria lọna ti ko bofinmu bẹrẹ lọjọ Ẹti nibi ti ẹlẹri kan lati ileeṣẹ idokoowo Naijiria, SEC ti jẹri.

Kí ni ìdájọ́ ilé ẹjọ́ àgbáyé, ICJ lórí ẹjọ́ tí South Africa pè tako ìwà ìpànìyàn ọlọ́gọ́ọ̀rọ̀ tí Israel hù, túmọ̀ sí?
Ilé ẹjọ́ tó ń gbọ́ ẹjọ́ náà ìyẹn International Court of Justice (ICJ) ni wọ́n ti ń ṣọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti ìgbà tí South Africa ti pe ẹjọ́ náà.

Lẹ́yìn tó lo ọdún 42, wọ́n sọ fún ọkùnrin adúláwọ̀ kan pé kìí ṣe ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
Nelson Shardey, ẹni to wa lati Wallasey ni Wirral lo ti lo ọpọlọpọ ọdun ni ilẹ UK pẹlu erongba pe oun ti di ọmọ ilu.

Ààrẹ Senegal ṣàbẹ̀wò sí Naijiria, pé fún àjọṣepọ̀ láàrin orílẹ̀èdè Áfíríkà
Aarẹ Faye ni aarẹ to kere lọjọ ju ni iwọ oorun ilẹ Afrika, to si wa se abẹwo si orilẹede Naijiria.

Àṣírí bí wọn ṣe ń fi òwò gẹdú ṣagbátẹrù ìgbésùmọ̀mí
Okoowo naa ti ko ba ofin mu ni iye owo ti wọn n pa nidi rẹ to miliọnu mẹtalelogun dolla lọdun.

Èèyàn kan sin ọmọ ìkókó láàyè, ó rò pé ìṣù ni
Abule Anshav Kusuv ni ipinlẹ Benue ni iṣẹlẹ naa ti waye nigba ti awọn ọdẹ aṣọgbo sawari ọmọ naa.

Wo àrà tí ẹgbẹ́ akọ̀rin tó jẹ́ kìkìdá obìnrin ń dá láì sí ọkùnrin kankan níbẹ̀
BBC Yorùbá fọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú Ayantummy, olórí ẹgbẹ́ akọ̀rin obìnrin àti ikọ̀ rẹ̀ láti mọ ìpèníjà tó ń kojú wọn ní agbo àwọn ọkùnrin tí wọn ti ń ṣiṣẹ́.

"A máa fún ọ ní N50m, gbé ọ pamọ loke okun, tó o bá fún wa ní ojúlówó ìròyìn nípa ohun tó pa Mohbad "
Ẹgbẹ African Television and Foundation for Justice ti kede pe oun yoo fun ẹni to ba sọ ojulowo ohun to pa Mohbad fun oun lati ran ileesẹ ọlọpaa lọwọ.

"N kò rò pé àjálù bàálù le kan Bàbá mi, mo ń fẹ́ ìdájọ́ òdodo lórí bàálù tó já ní 2019"
BBC bá obìnrin kan, Zipporah Kuria sọ̀rọ̀, ẹni ti bàbá rẹ̀ wà lára èrò 346 tó kú nínú ìjàmbá bàálù tó wáyé lọ́dún 2019, to sì ní òun fẹ́ ìdájọ́ òdodo.

Ìdí rèé tí èmi àti Peter Obi pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèlú míì ṣe fẹ́ lẹ̀pọ̀ saájú ìdìbò 2027 - Atiku
Atiku ni oun ko ni figba kankan fopin si jija fun ijọba awarawa lorilẹede Naijiria.

Aráàlú fárígá bí Olórí aṣòfin ṣe fẹ́ fi ọ̀dọ́bìnrin 100 tí kò ní òbí lọ́kọ láì ró wọn lágbára
Ọpọ eeyan lori ayelujara ti wọn jẹ ọmọ Naijiria ni wọn ti n binu si bi Olori ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Niger ṣe fẹẹ fi awọn ọmọbinrin ọgọrun-un (100) lọkọ.

Kí ni Portable kọ sínú orin tó gbé jáde lẹ́yìn tó kúrò ní àhámọ́ ọlọ́pàá?
Portable, lórí ìkànnì Instagram rẹ̀, lọ́jọ́bọ̀, ọjọ́ Kẹrìndínlógún, oṣù Karùn-ún, ọdún 2024 fi orin tó pé àkọ́lé rẹ̀ ní “Spiderman” síta láti fi sọ̀rọ̀ ohun tó gbe dé àhámọ́ ọlọ́pàá.

Ṣàńgbà fọ́, aráàlú kan yìnbọn ní ìgbà márùn-ún sí Olóòtù ìjọba Slovakia
Afurasi ọhun lo ti wa ni ahamọ lẹyin to yinbọn lu Fico.

Báwo ni ìjọ ẹ̀sìn mẹ́talọ́kàn ṣe di èyí tó ń dá èdèàìyedè sílẹ̀ láàrín àwọn aṣíwájú ẹ̀sìn Islam ní Ilorin?
Ọrọ naa ti n fa ọpọ ifanfa laarin awọn aṣiwaju ẹsin tọrọ kan.

Ọlọ́pàá Oyo fojú Auxiliary han síta, ó fẹ̀sùn ìjínigbé, ìdigunjalè àti ìṣekúpani kàn-án
Eṣun ijinigbe, iṣekupani ati idigunjale wa lara ẹsun ti wọn fi kan Auxillary pe wọn furasi pe o lọwọ ninu wọn.

Àwọn aláìsàn ọpọlọ tó ń gba ìtọ́jú ní Aro ṣe ìwọ́de, wọ́n gé dókítà jẹ yánna-yànna
Ohun ti a gbọ ni pe awọn to n gbatọju naa binu lori iwa tawọn alaṣẹ ati awọn dokita Aro n hu.

"Akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ òfin ni mi, kò sẹ́ni tó kọ́ mi níṣẹ́ àkàrà òyìnbò, orí ayélujára ni mo ti kọ́ ọ"
BBC Yoruba de ilu Ilorin lati ba Fawaz Aberuagba, tii se akẹkọọ nipa imọ ofin to tun n se akara oyinbo sọrọ lori idi to se pa isẹ mejeeji pọ.

₦48,000 owó oṣù tó kéré jùlọ tíjọba fẹ́ san fún òṣìṣẹ́ tàbùkù wá - Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ fọnmú
Aarẹ NLC, Joe Ajaero ṣalaye pe ijọba apapọ ko ti ṣetan lati duna dura lori iye ti owo oṣu to kere julọ yoo jẹ fawọn osisẹ ni Naijiria.

Portable gba ìtúsílẹ̀ ní àhámọ́ ọlọ́pàá, ó fi ọ̀rọ̀ síta
Agbẹnusọ Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko, Benjamin Hudenyin, ti wa fidi iroyin naa mulẹ pe Portable ti kuro ni ahamọ ọlọpaa.

Èsì àyẹ̀wó òkú Mohbad jáde, dókítà jẹ́rìí nílé ẹjọ́
Níbi ìgbẹ́jọ́ tó wáyé nílé ẹjọ́ lọ́jọ́rú, ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, oṣù Karùn-ún, ọdún 2024 ni dókítà tó ṣe àyẹ̀wò òkú náà ti wá sọ ohun tí èsì àyẹ̀wò náà wí.

Kí ló dé tí àjọ Ayánilówó Àgbáyé (IMF) ń tojú bọ ọrọ̀ ajé Naijiria?
Apẹẹrẹ bi wọn ṣe n da si ọrọ Naijiria ni imọran ti wọn gba Naijiria laipẹ yii, pe kijọba yee sanwo iranwọ lori ina, eyi ti ijọba si gba.

Ìlú kan rèé tí wọ́n ti máa ń rí àwọn èèyàn tó bọ́ lọ́wọ́ ìkọlù ààrá mọ́lẹ̀ láàyè
Ní ọjọ́ Àìkú ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ní agbègbè Melka Bello, ìlú kan tó wà ní kìlómítà 450 sí Addis Ababa tó jẹ́ olú ìlú orílẹ̀ èdè Ethiopia.

Àwọn ọmọ ìta wọ̀já ìjà l‘Osogbo, ẹ̀mí alágbe kan bá ìṣẹ̀lẹ̀ náà lọ
Aṣita ibọn awọn janduku ti sọ ọkunrin alagbe kan di ero ọrun ojiji bayii, laduugbo Gbaemu,Oṣogbo, nipinlẹ Ọṣun.

Mọ̀ nípa abẹ́rẹ́ tó ń dá ebi dúró, mú àdínkù bá ara sísán, tó sì ń dènà àìsàn ọkàn
Ọjọgbọn John Deanfield lo lewaju awọn oniwadii to se abẹrẹ naa sọ pe abẹrẹ yii le tun ni ipa nla lati mu ki ifunpa ati itọ suga eeyan wa silẹ, ti yoo si tun ṣe anfani nla fun ọkan.

Aráàlú fárígá bí Olórí aṣòfin ṣe fẹ́ fi ọ̀dọ́bìnrin 100 tí kò ní òbí lọ́kọ láì ró wọn lágbára
Ọpọ eeyan lori ayelujara ti wọn jẹ ọmọ Naijiria ni wọn ti n binu si bi Olori ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Niger ṣe fẹẹ fi awọn ọmọbinrin ọgọrun-un (100) lọkọ.





We always perform at our best when we work together

Our mission is to provide the means & technical know-how to accomplish the aforementioned with HUMILITAS - always



This Section Can Accommodate Your Adverts





Charleans In Celebration Mode

We have put an assorted mix of pics here for your enjoyment. We are always hungry for more - so if you have taken or have access to some pics remotely related to our issue, please do not hesitate to send them to the web admin team

SCOBA PARTNERS

corporates and enterprise businesses we have the pleasure to connect with.